Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni o sọ̀kalẹ, o si tẹ̀ ara rẹ̀ bọ inu Jordani nigba meje, gẹgẹ bi ọ̀rọ enia Ọlọrun: ẹran-ara rẹ̀ si tún pada bọ̀ gẹgẹ bi ẹran-ara ọmọ kekere, on si mọ́.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:10-24