Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Naamani binu, o si pada lọ, o si wipe, Kiyesi, i, mo rò ninu mi pe, dajudaju on o jade tọ̀ mi wá, yio si duro, yio si kepè orukọ Oluwa Ọlọrun rẹ̀, yio si fi ọwọ rẹ̀ pa ibẹ̀ na, yio si ṣe awòtan ẹ̀tẹ na.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:8-16