Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NJẸ Naamani, olori-ogun ọba Siria, jẹ enia nla niwaju oluwa rẹ̀, ati ọlọla, nitori nipa rẹ̀ ni Oluwa ti fi iṣẹgun fun Siria: on si jẹ alagbara akọni ọkunrin ṣugbọn adẹtẹ̀ ni.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:1-10