Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati iwọ ba si wọle, ki iwọ ki o se ilẹ̀kun mọ ara rẹ, ati mọ awọn ọmọ rẹ, ki o si dà a sinu gbogbo ikòko wọnni, ki iwọ ki o si fi eyiti o kún si apakan.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:1-7