Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si gòke, o si dubulẹ le ọmọ na, o si fi ẹnu rẹ̀ le ẹnu rẹ̀, ati oju rẹ̀ le oju rẹ̀, ati ọwọ rẹ̀ le ọwọ rẹ̀: on si nà ara rẹ̀ le ọmọ na, ara ọmọ na si di gbigboná.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:26-35