Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li o lọ, o si de ọdọ enia Ọlọrun na li òke Karmeli. O si ṣe, nigbati enia Ọlọrun na ri i li okère, o si sọ fun Gehasi ọmọ ọdọ rẹ̀ pe, Wò ara Ṣunemu nì:

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:17-30