Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si ke si ọkọ rẹ̀, o si wipe, Emi bẹ̀ ọ, rán ọkan ninu awọn ọdọmọkunrin si mi, ati ọkan ninu awọn kẹtẹkẹtẹ, emi o si sare tọ̀ enia Ọlọrun lọ, emi o si tun pada.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:13-27