Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Li akokò yi gẹgẹ bi igba aiye, iwọ gbé ọmọkunrin kan mọra. On si wipe, Bẹ̃kọ̀, oluwa mi, iwọ enia Ọlọrun, má ṣe purọ fun iranṣẹbinrin rẹ.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:6-18