Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wi fun u pe, nisisiyi, sọ fun u pe, Kiyesi i, iwọ ti fi gbogbo itọju yi ṣe aniyàn wa; kini a ba ṣe fun ọ? Iwọ nfẹ́ ki a sọ̀rọ rẹ fun ọba bi? tabi fun olori-ogun? On si dahùn wipe, Emi ngbe lãrin awọn enia mi.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:5-23