Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni ọba Israeli lọ, ati ọba Juda, ati ọba Edomu: nigbati nwọn rìn àrinyika ijọ meje, omi kò si si nibẹ fun awọn ogun, ati fun ẹranko ti ntọ̀ wọn lẹhin.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:8-18