Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si lọ, o ranṣẹ si Jehoṣafati ọba Juda, wipe, Ọba Moabu ti ṣọ̀tẹ si mi: iwọ o ha bá mi lọ si Moabu lati jagun? On si wipe, Emi o gòke lọ: emi bi iwọ, enia mi bi enia rẹ, ati ẹṣin mi bi ẹṣin rẹ.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:5-10