Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o mu akọbi ọmọ rẹ̀ ti iba jọba ni ipò rẹ̀, o si fi i rubọ sisun li ori odi. Ibinu nla si wà si Israeli: nwọn si lọ kuro lọdọ rẹ̀, nwọn si pada si ilẹ wọn.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:22-27