Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si de ibùdo Israeli, awọn ọmọ Israeli dide, nwọn si kọlù awọn ara Moabu, nwọn si sa kuro niwaju wọn: nwọn si wọ inu rẹ̀, nwọn si pa Moabu run.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:18-27