Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati gbogbo ara Moabu gbọ́ pe, awọn ọba gòke wá lati ba wọn jà, nwọn kó gbogbo awọn ti o le hamọra ogun jọ, ati awọn ti o dagba jù wọn lọ, nwọn si duro li eti ilẹ wọn.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:11-27