Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si kọlù gbogbo ilu olodi, ati gbogbo ãyò ilu, ẹnyin o si ké gbogbo igi rere lulẹ, ẹnyin o si dí gbogbo kanga omi, ẹnyin o si fi okuta bà gbogbo oko rere jẹ.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:13-27