Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi, pe, Ẹnyin kì o ri afẹfẹ, bẹ̃ni ẹnyin kì o ri òjo; ṣugbọn afonifojì na yio kún fun omi, ki ẹnyin ki o le mu, ati ẹnyin, ati awọn ẹran-ọ̀sin nyin, ati ẹran nyin.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:9-24