Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliṣa si wipe, Bi Oluwa awọn ọmọ-ogun ti mbẹ, niwaju ẹniti emi duro, iba má ṣepe mo bu ọwọ Jehoṣafati ọba Juda, nitõtọ emi kì ba ti bẹ̀ ọ wò, bẹ̃ni emi kì ba ti ri ọ.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:10-23