Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 3:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehoṣafati si wipe, Ọ̀rọ Oluwa mbẹ pẹlu rẹ̀. Bẹ̃ni ọba Israeli ati Jehoṣafati ati ọba Edomu sọ̀kalẹ tọ̀ ọ lọ.

2. A. Ọba 3

2. A. Ọba 3:10-19