Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li oṣù karun, li ọjọ keje oṣù, ti iṣe ọdun ikọkandilogun Nebukadnessari ọba, ọba Babeli, ni Nebusaradani olori ẹ̀ṣọ, iranṣẹ ọba Babeli, wá si Jerusalemu:

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:2-11