Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ilu na si fọ́, gbogbo awọn ọkunrin ologun si gbà ọ̀na bodè lãrin odi meji, ti o wà leti ọgbà ọba, salọ li oru; (awọn ara Kaldea si yi ilu na kakiri;) ọba si ba ọ̀na pẹ̀tẹlẹ lọ.

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:1-14