Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li ọdun kẹtadilogoji igbèkun Jehoiakini ọba Juda, li oṣù kejila, li ọjọ kẹtadilọgbọn oṣù, Efil-merodaki ọba Babeli, li ọdun ti o bẹ̀rẹ si ijọba, o gbé ori Jehoiakini ọba Juda soke kuro ninu tubu;

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:17-30