Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lati inu ilu, o mu iwẹ̀fa kan ti a fi ṣe olori awọn ologun, ati ọkunrin marun ninu awọn ti o wà niwaju ọba, ti a ri ni ilu, ati akọwe olori ogun, ti ntò awọn enia ilẹ na, ati ọgọta ọkunrin ninu awọn enia ilẹ na ti a ri ni ilu.

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:17-23