Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ọdun mejidilogun ni Jehoiakini nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba li oṣù mẹta ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ ni Nehuṣta, ọmọbinrin Elnatani ti Jerusalemu.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:1-12