Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọjọ rẹ̀ ni Nebukadnessari ọba Babeli gòke wá, Jehoiakimu si di iranṣẹ rẹ̀ li ọdun mẹta: nigbana li o pada o si ṣọ̀tẹ si i.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:1-10