Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbé ere-oriṣa jade kuro ni ile Oluwa, sẹhin ode Jerusalemu lọ si odò Kidroni, o si sun u nibi odò Kidroni, o si lọ̀ ọ lũlu, o si dà ẽrú rẹ̀ sori isà-okú awọn ọmọ enia na.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:1-11