Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ọdun mẹtalelogun ni Jehoahasi nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba; o si jọba li oṣù mẹta ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ ni Hamutali, ọmọbinrin Jeremiah ti Libna,

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:29-34