Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kò si si ọba kan ṣãju rẹ̀, ti o dabi rẹ̀, ti o yipada si Oluwa tinutinu ati tọkàntọkàn ati pẹlu gbogbo agbara rẹ̀, gẹgẹ bi gbogbo ofin Mose; bẹ̃ni lẹhin rẹ̀, kò si ẹnikan ti o dide ti o dàbi rẹ̀.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:17-29