Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si gòke lọ sinu ile Oluwa, ati gbogbo awọn enia Juda ati gbogbo olugbe Jerusalemu pẹlu rẹ̀, ati awọn alufa, ati awọn woli ati gbogbo enia, ati ewe ati àgba: o si kà gbogbo ọ̀rọ inu iwe majẹmu na ti a ri ninu ile Oluwa li eti wọn.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:1-8