Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fọ́ awọn ere na tũtu, o si wó awọn ere-oriṣa lulẹ, o si fi egungun enia kún ipò wọn.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:11-24