Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 21:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ẸNI ọdun mejila ni Manasse nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba li ọdun marundilọgọta ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ ni Hefsiba.

2. A. Ọba 21

2. A. Ọba 21:1-3