Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:24-25 Yorùbá Bibeli (YCE)

24. O si yipada, o si wò wọn, o si fi wọn bú li orukọ Oluwa. Abo-beari meji si jade lati inu igbó wá, nwọn si fà mejilelogoji ya ninu wọn.

25. O si ti ibẹ lọ si òke Karmeli; ati lati ibẹ o pada si Samaria.