Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin ilu na si wi fun Eliṣa pe, Kiyesi i, itẹ̀do ilu yi dara, bi oluwa mi ti ri i: ṣugbọn omi buru, ilẹ si ṣá.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:18-22