Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 2:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si rọ̀ ọ titi oju fi tì i, o wi fun wọn pe, Ranṣẹ. Nitorina nwọn rán ãdọta ọkunrin, nwọn si wá a ni ijọ mẹta, ṣugbọn nwọn kò ri i.

2. A. Ọba 2

2. A. Ọba 2:15-18