Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Isaiah si wi fun wọn pe, Bayi ni ki ẹ sọ fun oluwa nyin, Bayi li Oluwa wi pe, Máṣe bẹ̀ru ọ̀rọ wọnni, ti o ti gbọ́, ti awọn iranṣẹ ọba Assiria fi sọ ọ̀rọ odi si mi.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:3-13