Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi o ti mbọ̀riṣa ni ile Nisroku oriṣa rẹ̀, ni Adrammeleki ati Ṣareseri awọn ọmọ rẹ̀ fi idà pa a: nwọn si sa lọ si ilẹ Armenia. Esarhaddoni ọmọ rẹ̀ sì jọba ni ipò rẹ̀.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:29-37