Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li oru na ni angeli Oluwa jade lọ, o si pa ọkẹ́ mẹsan le ẹgbẹ̃dọgbọn enia ni ibùbo awọn ara Assiria: nigbati nwọn si dide ni kutukutu owurọ, kiyesi i, okú ni gbogbo wọn jasi.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:28-37