Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ kò ti gbọ́, lailai ri emi ti ṣe e, nigba atijọ emi si ti mura tẹlẹ nisisiyi emi ti mu u ṣẹ, ki iwọ ki o le mã sọ ilu olodi wọnni di ahoro, ani di òkiti àlapa.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:16-33