Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si ti gbe òriṣa wọn sọ sinu iná; nitoriti nwọn kì iṣe ọlọrun, bikòṣe iṣẹ ọwọ enia, igi ati okuta: nitorina ni nwọn ṣe pa wọn run.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:13-27