Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hesekiah si gbà iwe na lọwọ awọn onṣẹ na, o si kà a: Hesekiah si gòke lọ sinu ile Oluwa, o si tẹ́ ẹ siwaju Oluwa.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:6-24