Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

On mu ibi giga wọnni kuro, o si fọ́ awọn ere, o si wó awọn ere oriṣa lulẹ, o si fọ́ ejò idẹ na tútu ti Mose ti ṣe: nitori titi di ọjọ wọnni, awọn ọmọ Israeli nsun turari si i: a si pè e ni Nehuṣtani.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:1-11