Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nibo li awọn oriṣa Hamati, ati Arpadi gbe wà? Nibo li awọn oriṣa Sefarfaimu, Hena, ati Ifa gbe wà? Nwọn ha gbà Samaria kuro lọwọ mi bi?

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:29-37