Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ máṣe jẹ ki Hesekiah mu nyin gbẹkẹle Oluwa, wipe, Ni gbigbà Oluwa yio gbà wa, a kì yio si fi ilu yi le ọba Assiria lọwọ.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:29-37