Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Eliakimu ọmọ Hilkiah, ati Ṣebna, ati Joa wi fun Rabṣake pe, Emi bẹ̀ ọ, ba awọn iranṣẹ rẹ sọ̀rọ li ède Siria; nitoriti awa gbọ́ ọ: ki o má si ṣe ba wa sọ̀rọ li ède Juda li leti awọn enia ti mbẹ lori odi.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:23-34