Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, nisisiyi, iwọ gbẹkẹle ọ̀pa iyè fifọ yi, ani le Egipti, lara ẹniti bi ẹnikan ba fi ara tì, yio wọ̀ ọ li ọwọ lọ, yio si gun u: bẹ̃ni Farao ọba Egipti ri fun gbogbo awọn ti o gbẹkẹ wọn le e.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:15-28