Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ọdun mẹ̃dọgbọ̀n li on nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba; o si jọba li ọdun mọkandilọgbọ̀n ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ ni Abi ọmọbinrin Sakariah.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:1-7