Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hesekiah ọba Juda si ranṣẹ si ọba Assiria ni Lakiṣi, wipe, Mo ti ṣẹ̀; padà lẹhin mi: eyiti iwọ ba bù fun mi li emi o rù. Ọba Assiria si bù ọ̃dunrun talenti fadakà, ati ọgbọ̀n talenti wura fun Hesekiah ọba Juda.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:13-19