Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọdun kẹsan Hoṣea, ni ọba Assiria kó Samaria, o si kó Israeli lọ si Assiria, o si fi wọn si Hala ati si Habori, leti odò Gosani, ati si ilu awọn ara Media.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:4-9