Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Assiria si ri ọ̀tẹ ninu Hoṣea: nitoriti o ti rán onṣẹ sọdọ So ọba Egipti, kò si mu ọrẹ fun ọba Assiria wá bi iti mã iṣe li ọdọdun; nitorina ni ọba Assiria há a mọ, o si dè e ni ile tubu.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:3-5