Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Assiria si kó enia lati Babeli wá, ati lati Kuta, ati lati Afa, ati lati Hamati, ati lati Sefarfaimi, o si fi wọn sinu ilu Samaria wọnni, ni ipò awọn ọmọ Israeli; nwọn si ni Samaria, nwọn si ngbe inu rẹ̀ wọnni.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:16-31