Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nibẹ ni nwọn si sun turari ni gbogbo ibi giga wọnni, bi awọn keferi ti Oluwa kó lọ niwaju wọn ti ṣe; nwọn si ṣe ohun buburu lati rú ibinu Oluwa soke.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:8-12